Yoruba Bible
2 Corinthians 12:10
Nitorina emi ni inu didùn ninu ailera gbogbo, ninu ẹ̀gan gbogbo, ninu aini gbogbo, ninu inunibini gbogbo, ninu wahalà gbogbo nitori Kristi: nitori nigbati mo ba jẹ alailera, nigbana ni mo di alagbara. Paulu Ní Àníyàn fún Ìjọ Kọrinti
Open Bible reader