Skip to content

Yoruba Bible

2 Chronicles 7:10

Ati li ọjọ kẹtalelogun oṣù keje, o rán awọn enia pada lọ sinu agọ wọn, pẹlu ayọ̀ ati inudidùn nitori ore-ọfẹ ti Oluwa ti fi hàn fun Dafidi, ati fun Solomoni, ati fun Israeli, enia rẹ̀. Ọlọrun Tún Farahan Solomoni (1. A. Ọba 9:1-9)

Open Bible reader