Skip to content

Yoruba Bible

2 Chronicles 5:10

Kò si ohun kan ninu apoti-ẹri na bikòṣe walã meji ti Mose fi sinu rẹ̀ ni Horebu, nigbati Oluwa fi ba awọn ọmọ Israeli dá majẹmu, nigbati nwọn ti Egipti jade wá. Ògo OLUWA

Open Bible reader