Yoruba Bible
2 Chronicles 36:8
Ati iyokù iṣe Jehoiakimu ati awọn ohun-irira rẹ̀ ti o ti ṣe, ti a si ri ninu rẹ̀, kiyesi i, a kọ wọn sinu iwe awọn ọba Israeli ati Juda: Jehoiakini, ọmọ rẹ̀, si jọba ni ipò rẹ̀. Jehoiakini, Ọba Juda (2 Awon Ọba 24:8-17)
Open Bible reader