Yoruba Bible
2 Chronicles 34:7
Nigbati o si fọ́ awọn pẹpẹ ati ère-oriṣa dilẹ, ti o si ti gún awọn ere yiyá di ẹ̀tu, ti o si ti ké gbogbo awọn ère-õrun lulẹ ni gbogbo ilẹ Israeli, o pada si Jerusalemu. Wọ́n Rí Ìwé Òfin (2 Awon Ọba 22:3-20)
Open Bible reader