Yoruba Bible
2 Chronicles 34:28
Kiyesi i, emi o kó ọ jọ sọdọ awọn baba rẹ, a o si kó ọ jọ si isa-okú rẹ li alafia, bẹ̃ni oju rẹ kì yio ri gbogbo ibi ti emi o mu wá si ihinyi, ati sori awọn ti ngbe ibẹ. Bẹ̃ni nwọn mu èsi pada fun ọba wá. Josaya Dá Majẹmu láti Tẹ̀lé OLUWA (2 Awon Ọba 23:1-20)
Open Bible reader