Skip to content

Yoruba Bible

2 Chronicles 32:31

Ṣugbọn niti awọn ikọ̀ awọn ọmọ-alade Babeli, ti nwọn ranṣẹ si i, lati bère ohun-iyanu ti a ṣe ni ilẹ na, Ọlọrun fi i silẹ lati dán a wò, ki o le mọ̀ ohun gbogbo ti o wà li ọkàn rẹ̀. Ìgbẹ̀yìn Ìjọba Hesekaya (2 Awon Ọba 20:20-21)

Open Bible reader