Skip to content

Yoruba Bible

2 Chronicles 21:1

JEHOṢAFATI si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, a si sìn i pẹlu awọn baba rẹ̀ ni ilu Dafidi: Jehoramu ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀. Jehoramu, Ọba Juda (2. A. Ọba 8:17-24)

Open Bible reader