Yoruba Bible
1 Kings 12:20
O si ṣe nigbati gbogbo Israeli gbọ́ pe Jeroboamu tun pada bọ̀, ni nwọn ranṣẹ, nwọn si pè e wá si ajọ, nwọn si fi i jọba lori gbogbo Israeli: kò si ẹnikan ti o tọ̀ ile Dafidi lẹhin, bikoṣe kiki ẹya Juda. Àsọtẹ́lẹ̀ Ṣemaaya (2 Kron 11:1-4)
Open Bible reader