Yoruba Bible
1 Kings 10:13
Solomoni ọba si fun ayaba Ṣeba ni gbogbo ifẹ rẹ̀, ohunkohun ti o bère, li aika eyiti a fi fun u lati ọwọ Solomoni ọba wá. Bẹ̃li o si yipada, o si lọ si ilu rẹ̀, on, ati awọn iranṣẹ rẹ̀. Ọrọ̀ Solomoni Ọba (2. Kron 9:13-29)
Open Bible reader