Skip to content

Yoruba Bible

1 John 3:10

Ninu eyi li awọn ọmọ Ọlọrun nfarahan, ati awọn ọmọ Èṣu: ẹnikẹni ti kò ba nṣe ododo kì iṣe ti Ọlọrun, ati ẹniti kò fẹràn arakunrin rẹ̀. Ẹ Fẹ́ràn Ẹnìkejì Yín

Open Bible reader