Skip to content

Yoruba Bible

1 Chronicles 20:3

O si kó awọn enia ti o wà nibẹ jade wá, o si fi ayùn ati irin mimu ati ãke ké wọn. Aní bayi ni Dafidi ṣe si gbogbo ilu awọn ọmọ Ammoni. Ati Dafidi ati gbogbo awọn enia pada bọ̀ si Jerusalemu. Bíbá Àwọn Òmìrán Filistini Jagun (2 Sam 21:15-22)

Open Bible reader