Skip to content

Psalms 70 - Listen Online

Loading Bible...
Read Psalms 70

1 ỌLỌRUN, yara gbà mi; Oluwa, yara lati ràn mi lọwọ.

1 Make haste, O God, to deliver me; make haste to help me, O LORD.

2 Ki oju ki o tì awọn ti nwá ọkàn mi, ki nwọn ki o si dãmu: ki nwọn ki o si pada sẹhin, ki a si dãmu awọn ti nwá ifarapa mi.

2 Let them be ashamed and confounded that seek after my soul: let them be turned backward, and put to confusion, that desire my hurt.

3 Ki a pa wọn li ẹhìn dà fun ère itiju awọn ti nwi pe, A! a!

3 Let them be turned back for a reward of their shame that say, Aha, aha.

4 Ki gbogbo awọn ti nwá ọ ki o ma yọ̀, ki inu wọn ki o si ma dùn nipa tirẹ: ki iru awọn ti o si fẹ igbala rẹ ki o ma wi nigbagbogbo pe, Ki a gbé Ọlọrun ga!

4 Let all those that seek thee rejoice and be glad in thee: and let such as love thy salvation say continually, Let God be magnified.

5 Ṣugbọn talaka ati alaini li emi: Ọlọrun, yara si mi: iwọ li oluranlọwọ ati olugbala mi: Oluwa, máṣe pẹ́ titi.

5 But I am poor and needy: make haste unto me, O God: thou art my help and my deliverer; O LORD, make no tarrying.