Skip to content

Psalms 23 - Listen Online

Loading Bible...
Read Psalms 23

1 OLUWA li Oluṣọ-agutan mi; emi kì yio ṣe alaini.

1 The LORD is my shepherd; I shall not want.

2 O mu mi dubulẹ ninu papa-oko tutù; o mu mi lọ si iha omi didakẹ rọ́rọ́.

2 He maketh me to lie down in green pastures: he leadeth me beside the still waters.

3 O tù ọkàn mi lara; o mu mi lọ nipa ọ̀na ododo nitori orukọ rẹ̀.

3 He restoreth my soul: he leadeth me in the paths of righteousness for his name's sake.

4 Nitõtọ, bi mo tilẹ nrìn larin afonifoji ojiji ikú, emi kì yio bẹ̀ru ibi kan; nitori ti Iwọ pẹlu mi; ọgọ rẹ ati ọpá rẹ nwọn ntù mi ninu.

4 Yea, though I walk through the valley of the shadow of death, I will fear no evil: for thou art with me; thy rod and thy staff they comfort me.

5 Iwọ tẹ́ tabili onjẹ silẹ niwaju mi li oju awọn ọta mi; iwọ dà ororo si mi li ori; ago mi si kún akúnwọsilẹ.

5 Thou preparest a table before me in the presence of mine enemies: thou anointest my head with oil; my cup runneth over.

6 Nitotọ, ire ati ãnu ni yio ma tọ̀ mi lẹhin li ọjọ aiye mi gbogbo; emi o si ma gbe inu ile Oluwa lailai.

6 Surely goodness and mercy shall follow me all the days of my life: and I will dwell in the house of the LORD for ever.