DaBible
Psalms 24:7
Yoruba
Ẹ gbé ori nyin soke, ẹnyin ẹnu-ọ̀na; ki a si gbé nyin soke, ẹnyin ilẹkun aiyeraiye: ki Ọba ogo ki o wọ̀ inu ile wa.
English / KJV
Lift up your head, O ye gates; and be ye lift up, ye everlasting doors; and the King of glory shall come in.