DaBible
Mark 10:12
Yoruba
Bi obinrin kan ba si fi ọkọ rẹ̀ silẹ, ti a ba si gbé e ni iyawo fun ẹlomiran, o ṣe panṣaga. Jesu Súre Fun Àwọn Ọmọde (Mat 19:13-15; Luk 18:15-17)
English / KJV
And if a woman shall put away her husband, and be married to another, she committeth adultery.