DaBible
Luke 14:24
Yoruba
Nitori mo wi fun nyin, Ẹnikẹni ninu awọn enia wọnyi ti a ti pè, ki yio tọwò ninu àse-alẹ mi. Ohun Tí Eniyan Gbọdọ̀ Ṣe Kí Ó Tó Lè Jẹ́ Ọmọ-ẹ̀hìn (Mat 10:37-38)
English / KJV
For I say unto you, That none of those men which were bidden shall taste of my supper.