Skip to content

DaBible

Leviticus 24:9

Yoruba

Ki o si ma jẹ́ ti Aaroni ati ti awọn ọmọ rẹ; ki nwọn ki o si ma jẹ ẹ ni ibi mimọ́ kan: nitoripe mimọ́ julọ ni fun u ninu ẹbọ OLUWA ti a fi iná ṣe, ìlana titilai. Àpẹẹrẹ Ìdájọ́ ati Ìjẹníyà Tí Ó Tọ́

English / KJV

And it shall be Aaron's and his sons'; and they shall eat it in the holy place: for it is most holy unto him of the offerings of the LORD made by fire by a perpetual statute.

Download DaBible

Read online