DaBible
Job 9:20
Yoruba
Bi mo tilẹ da ara mi lare, ẹnu ara mi ni yio dá mi lẹbi; bi mo wipe, olododo li emi, yio si fi mi hàn ni ẹni-òdi.
English / KJV
If I justify myself, mine own mouth shall condemn me: if I say, I am perfect, it shall also prove me perverse.