Skip to content

DaBible

Jeremiah 36:10

Yoruba

Baruku si ka ọ̀rọ Jeremiah lati inu iwe ni ile Oluwa, ni iyara Gemariah, ọmọ Ṣafani, akọwe, ni àgbala oke, nibi ilẹkun ẹnu-ọ̀na titun ile Oluwa li eti gbogbo enia. Wọ́n ka Àkọsílẹ̀ náà sí Etígbọ̀ọ́ Àwọn Ìjòyè

English / KJV

Then read Baruch in the book the words of Jeremiah in the house of the LORD, in the chamber of Gemariah the son of Shaphan the scribe, in the higher court, at the entry of the new gate of the LORD's house, in the ears of all the people.

Download DaBible

Read online