DaBible
James 2:8
Yoruba
Ṣugbọn bi ẹnyin ba nmu olú ofin nì ṣẹ gẹgẹ bi iwe-mimọ́, eyini ni, Iwọ fẹ ẹnikeji rẹ bi ara rẹ, ẹnyin nṣe daradara.
English / KJV
If ye fulfil the royal law according to the scripture, Thou shalt love thy neighbour as thyself, ye do well: