DaBible
Isaiah 59:8
Yoruba
Ọ̀na alafia ni nwọn kò mọ̀; kò si idajọ kan ninu ìrin wọn: nwọn ṣe ipa-ọ̀na wiwọ́ fun ara wọn: ẹnikẹni ti o ba tọ̀ ọ kì yio mọ̀ alafia. Àwọn Eniyan Jẹ́wọ́ Ẹ̀ṣẹ̀ wọn
English / KJV
The way of peace they know not; and there is no judgment in their goings: they have made them crooked paths: whosoever goeth therein shall not know peace.