DaBible
Isaiah 59:15
Yoruba
Otitọ kò si, ẹniti o si kuro ninu ibi o sọ ara rẹ̀ di ijẹ: Oluwa si ri i, o si buru loju rẹ̀, ti idajọ kò si. OLUWA Ṣetán láti Gba Àwọn Eniyan Rẹ̀
English / KJV
Yea, truth faileth; and he that departeth from evil maketh himself a prey: and the LORD saw it, and it displeased him that there was no judgment.