DaBible
Hosea 1:9
Yoruba
Nigbana ni Ọlọrun wipe, Pè orukọ rẹ̀ ni Loammi; nitori ẹnyin kì iṣe enia mi, emi kì yio si ṣe Ọlọrun nyin. A óo Ra Israẹli Pada
English / KJV
Then said God, Call his name Lo-ammi: for ye are not my people, and I will not be your God.