DaBible
Exodus 21:2
Yoruba
Bi iwọ ba rà ọkunrin Heberu li ẹrú, ọdún mẹfa ni on o sìn: li ọdún keje yio si jade bi omnira lọfẹ.
English / KJV
If thou buy an Hebrew servant, six years he shall serve: and in the seventh he shall go out free for nothing.