DaBible
Daniel 3:18
Yoruba
Ṣugbọn bi bẹ̃kọ, ki o ye ọ, ọba pe, awa kì yio sìn oriṣa rẹ, bẹ̃li awa kì yio si tẹriba fun ere wura ti iwọ gbé kalẹ. Wọ́n Dá Ẹjọ́ Ikú fún Àwọn Ọ̀rẹ́ Daniẹli Mẹtẹẹta
English / KJV
But if not, be it known unto thee, O king, that we will not serve thy gods, nor worship the golden image which thou hast set up.