DaBible
Amos 9:10
Yoruba
Gbogbo awọn ẹlẹṣẹ ninu enia mi yio ti ipa idà kú, ti nwipe, Ibi na kì yio le wa ba, bẹ̃ni kì yio ba wa lojijì. Dídá Israẹli Pada Sípò Lọ́jọ́ Iwájú
English / KJV
All the sinners of my people shall die by the sword, which say, The evil shall not overtake nor prevent us.