DaBible
Amos 2:5
Yoruba
Ṣugbọn emi o rán iná kan sara Juda, yio si jó ãfin Jerusalemu wọnni run. Ìdájọ́ Ọlọrun lórí Israẹli
English / KJV
But I will send a fire upon Judah, and it shall devour the palaces of Jerusalem.