DaBible
2 Kings 23:20
Yoruba
O si pa gbogbo awọn alufa ibi-giga wọnni ti o wà nibẹ lori awọn pẹpẹ na, o si sun egungun enia lori wọn, o si pada si Jerusalemu. Josaya Ọba ṣe Àjọ̀dún Àjọ Ìrékọjá (2 Kron 35:1-19)
English / KJV
And he slew all the priests of the high places that were there upon the altars, and burned men's bones upon them, and returned to Jerusalem.