Skip to content

DaBible

2 Chronicles 4:4

Yoruba

O duro lori malu mejila wọnni, mẹta nwò iha ariwa, ati mẹta nwò iwọ-õrun, ati mẹta nwò gusu ati mẹta nwò iha ilà-orun: a si gbé agbada na ka ori wọn, gbogbo iha ẹhin wọn si wà ninu.

English / KJV

It stood upon twelve oxen, three looking toward the north, and three looking toward the west, and three looking toward the south, and three looking toward the east: and the sea was set above upon them, and all their hinder parts were inward.

Download DaBible

Read online