DaBible
2 Chronicles 33:20
Yoruba
Manasse si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, nwọn si sìn i si ile on tikalarẹ̀: Amoni, ọmọ rẹ̀, si jọba ni ipò rẹ̀. Amoni, Ọba Juda (2 Awon Ọba 21:19-26)
English / KJV
So Manasseh slept with his fathers, and they buried him in his own house: and Amon his son reigned in his stead.