Skip to content

DaBible

2 Chronicles 30:12

Yoruba

Ni Judah pẹlu, ọwọ Ọlọrun wà lati fun wọn li ọkàn kan lati pa ofin ọba mọ́ ati ti awọn ijoye, nipa ọ̀rọ Oluwa. Àsè Àjọ Ìrékọjá

English / KJV

Also in Judah the hand of God was to give them one heart to do the commandment of the king and of the princes, by the word of the LORD.

Download DaBible

Read online