DaBible
2 Chronicles 16:10
Yoruba
Asa si binu si ariran na, o si fi i sinu tubu; nitoriti o binu si i niti eyi na. Asa si ni ninu awọn enia na lara li akokò na. Òpin Ìjọba Asa (1. A. Ọba 15:23-24)
English / KJV
Then Asa was wroth with the seer, and put him in a prison house; for he was in a rage with him because of this thing. And Asa oppressed some of the people the same time.