DaBible
1 Kings 8:61
Yoruba
Nitorina, ẹ jẹ ki aìya nyin ki o pé pẹlu Oluwa Ọlọrun wa, lati mã rìn ninu aṣẹ rẹ̀, ati lati pa ofin rẹ̀ mọ́, bi ti oni yi. Yíya ilé OLUWA sí mímọ́ (2 Kron 7:4-10)
English / KJV
Let your heart therefore be perfect with the LORD our God, to walk in his statutes, and to keep his commandments, as at this day.