Skip to content

DaBible

1 Kings 8:21

Yoruba

Emi si ti ṣe àye kan nibẹ̀ fun apoti-ẹri, ninu eyiti majẹmu Oluwa gbe wà, ti o ti ba awọn baba wa dá, nigbati o mu wọn jade lati ilẹ Egipti wá. Adura Solomoni (2 Kron 6:12-42)

English / KJV

And I have set there a place for the ark, wherein is the covenant of the LORD, which he made with our fathers, when he brought them out of the land of Egypt.

Download DaBible

Read online