DaBible
1 Kings 16:14
Yoruba
Ati iyokù iṣe Ela, ati gbogbo ohun ti o ṣe, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Israeli? Simiri, Ọba Israẹli
English / KJV
Now the rest of the acts of Elah, and all that he did, are they not written in the book of the chronicles of the kings of Israel?