DaBible
1 Chronicles 9:27
Yoruba
Nwọn a si ma sùn yi ile Ọlọrun ka, nitori ti nwọn ni itọju na, ati ṣiṣi rẹ̀ li orowurọ jẹ ti wọn. Àwọn Ọmọ Lefi Yòókù
English / KJV
And they lodged round about the house of God, because the charge was upon them, and the opening thereof every morning pertained to them.