DaBible
1 Chronicles 6:48
Yoruba
Arakunrin wọn pẹlu, awọn ọmọ Lefi, li a yàn si oniruru iṣẹ gbogbo ti agọ ile Ọlọrun. Ìran Aaroni
English / KJV
Their brethren also the Levites were appointed unto all manner of service of the tabernacle of the house of God.