Skip to content

DaBible

1 Chronicles 11:11

Yoruba

Eyi ni iye awọn ọkunrin akọni ti Dafidi ni; Jaṣobeamu ọmọ Hakmoni, olori ninu awọn ọgbọ̀n balogun: on li o gbé ọ̀kọ rẹ̀ soke si ọ̃dunrun enia ti o pa lẹrikan.

English / KJV

And this is the number of the mighty men whom David had; Jashobeam, and Hachmonite, the chief of the captains: he lifted up his spear against three hundred slain by him at one time.

Download DaBible

Read online